Orikis e aduras
Egungun
Oriki Egungun
IBA
IBA MI
IBA RÉ
EXU LAALU OGIRI OKO, IBA
IBA AGBA
OLOJO TO NI NMA GBE ORI ILE SE TEMI
EYIN TO NI AYIE IBA
IBA ENI SOJE KI NTO MORA SÉ
EDUN GBONRAGANDA
A GBE AYE GBE ORUN
ESA OGBIN
ARA ORUN KENKEN
OLOGBODJO BABA ATI INU ASO-SIKE
BABA MI OSO OLOGBODJO
A TO FI EDUN OKAN LO
PE TEMI WRE...